Yoruba Greetings and Self Introduction
Ikíni-Ijẹ́ni Greetings
Akókò Ọjọ́. Periods of the day
Òwúrọ̀. Morning
Ọ̀sán. Afternoon
Ìrọ̀lẹ́. Evening
Alẹ́. Night
Orú. Midnight
- Òwúrọ̀. Morning
Ikini: Ẹ kú òwúrọ̀ o / Ẹ kú àárọ
Greeting: Good Morning
Ijẹ́ni: O o
Response: Yes, good morning
Ikini: Ṣé dáadáa ni ẹ jí o ?
Greeting: How are you ?
Ijẹ́ni: A dúpẹ́ o
Response: Fine, Thank you
Ikini: Ara ò le bí ?
Greeting: Hope all is well with you
Ijẹ́ni: A dúpẹ́ o
Response: Fine, thank you
B. Ọsán. Afternoon
Ikini: Ẹ kú àsán / Ẹ káàsán o
Greeting: Good Afternoon
Ijẹ́ni:. O o
Response: Yes, good afternoon
Ikini: Ṣé dáadáa ni ?
Greeting: How are you ?
Ijẹ́ni: A dúpẹ́ o
Response: Fine, Thank you
C. Ìrọ̀lẹ́. Evening
Ikini: Ẹ kú Ìrọ̀lẹ́ o
Greeting: Good evening
Ijẹ́ni: A dúpẹ́ o
Response: Fine, Thank you
D. Alẹ́. Night
Ikini: Ẹ kú alẹ / Ẹ káalẹ́ o
Greeting: Good night
Ijẹ́ni: O o
Response:Yes, good night
Ikini: Ṣé dáadáa ni o ?
Greeting: How are you ?
Ijẹ́ni: A dúpẹ́ o
Response: Fine, Thank you
Ikini: O dàárọ̀ o
Greeting: Good night
Ijẹ́ni: O o
Response: Thank you
Ikini: Ká sùn un re o
Greeting: Happy night rest
Ijẹ́ni: Amin o
Response: Amen