Yoruba Words of Wisdom and Encouragement
Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́ [Work is the antidote for poverty]
Múra sí’ ṣẹ́ ọ̀rẹ́ẹ̀ mi [concentrate on your work, my friend]
Iṣẹ́ l’ afi ndẹni gíga [great work ethic leads to success]
Bí a kò bá r’ ẹ́ni fẹ̀hìntì [if we do not have anybody to rely on]
Bí ọ̀lẹ l’ àárí [we feel inadequate]
Bí a kò bá r’ẹni gb’ ẹ́kẹ̀lé [if we have no one to depend on]
A tẹra mọ́’ṣẹ́ ẹni [we should work even harder]
Ìyá rẹ lè l’ówó l’ọ́wọ́ [Your mother could be very rich]
Bàbá rẹ lè lẹ́shin léèkàn [Your dad could have horses in the stable]
Bí o bá gb’ ójú lé wọn [If you depend on them solely]
Oo tẹ́ tán ni mo sọ fún ọ [You could find yourself in deep trouble]
Oun tí a kò bá jìyà fún [What we do not suffer for]
Ṣé kìí nlè t’ọ́jọ́ [does not last long in our hands]
Oun t’ábá fara ṣ’iṣẹ́ fún [something that we really work hard to achieve]
Níí pẹ́ l’ọ́wọ́ ẹni [will last long in our hands]
Apá lará, ìgùnpa ni iyèkan [our arms signify our friends, our elbows signify our family]
B’ áyé bá nfẹ́ ọ lónìí [when the world praises you today]
Bí o bá l’ówó l’ọ́wọ́ [if you become rich and successful]
Ayé á máa fẹ ọ l’ọ́la [the world will always want to be your friend]
Tàbí kí o wà ní ipò àtàtà [or should you be in an enviable position]
Ayé á máa yẹ́ ọ sí t’ẹ̀rin t’ẹ̀rin [the world impress you with smiles and laughter]
Jẹ́ k’o d’ẹni tí n ráágó [should the table turn and you become penniless]
K’o ri b’ayé ṣe nyinmú sí ọ [come see as people will mock you]
Ẹ̀kọ́ sì tún sọni d’ọ̀gá [work could turn you into a boss]
Múra ki o kọ́ọ dáradára [persevere to do your work diligently]
Ìyà nbọ f’ọ́mọ tí kò gbọ́ [hard times are coming for the irresponsible child]
Ẹkún nbẹ f’ọ́mọ tí nsá kiri [crying and weeping awaits the wayward child]
Má f’ọ̀wúrọ̀ ṣe’ré ọ̀rẹ́ mi [do not play with your future]
Múra si’ṣẹ ọjọ́ nlọ [be persistent, time waits for no one]
Culled from Alawiye Apa K’eji authored by Chief J.F. Odunjo
Yoruba Words of Wisdom and Encouragement in Yoruba
Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́
Múra sí’ ṣẹ́ ọ̀rẹ́ẹ̀ mi
Iṣẹ́ l’ afi ndẹni gíga
Bí a kò bá r’ ẹ́ni fẹ̀hìntì
Bí ọ̀lẹ l’ àárí
Bí a kò bá r’ẹni gb’ ẹ́kẹ̀lé
A tẹra mọ́’ṣẹ́ ẹni
Ìyá rẹ lè l’ówó l’ọ́wọ́
Bàbá rẹ lè lẹ́shin léèkàn
Bí o bá gb’ ójú lé wọn
Oo tẹ́ tán ni mo sọ fún ọ
Oun tí a kò bá jìyà fún
Ṣé kìí nlè t’ọ́jọ́
Oun t’ábá fara ṣ’iṣẹ́ fún
Níí pẹ́ l’ọ́wọ́ ẹni
Apá lará, ìgùnpa ni iyèkan
B’ áyé bá nfẹ́ ọ lónìí
Bí o bá l’ówó l’ọ́wọ́
Ayé á máa fẹ ọ l’ọ́la
Tàbí kí o wà ní ipò àtàtà
Ayé á máa yẹ́ ọ sí t’ẹ̀rin t’ẹ̀rin
Jẹ́ k’o d’ẹni tí n ráágó
K’o ri b’ayé ṣe nyinmú sí ọ
Ẹ̀kọ́ sì tún sọni d’ọ̀gá
Múra ki o kọ́ọ dáradára
Ìyà nbọ f’ọ́mọ tí kò gbọ́
Ẹkún nbẹ f’ọ́mọ tí nsá kiri
Má f’ọ̀wúrọ̀ ṣe’ré ọ̀rẹ́ mi
Múra si’ṣẹ ọjọ́ nlọ
Culled from Alawiye Apa K’eji authored by Chief J.F. Odunjo
Yoruba Words of Wisdom and Encouragement Interpretation in English
Work is the antidote for poverty
Concentrate on your work, my friend
Great work ethic leads to success
If we do not have anybody to rely on
We feel inadequate
If we have no one to depend on
We should work even harder
Your mother could be very rich
Your dad could have horses in the stable
If you depend on them solely
You could find yourself in deep trouble
What we do not suffer for
Does not last long in our hands
Something that we really work hard to achieve
Will last long in our hands
Our arms signify our friends, our elbows signify our family
When the world praises you today
If you become rich and successful
The world will always want to be your friend
Or should you be in an enviable position
The world impress you with smiles and laughter
Should the table turn and you become penniless
Come see as people will mock you
Work could turn you into a boss
Persevere to do your work diligently
Hard times are coming for the irresponsible child
Crying and weeping awaits the wayward child
Do not play with your future
Be persistent, time waits for no one