Oba Esinlokun reigned as Oba of Lagos from 1780 to 1819. His father was Oba Ologun Kutere and his siblings were Obas Adele, Akitoye, Prince Olusi and Prince Akiolu making the Ologun Kutere Obaship line the dominant one in Lagos.[1] Eshinlokun had sixteen children who survived him. They are in the order of seniority: Kosoko, Olufunmi, Odunsi, Ladega, Ogunbambi, Akinsanya, Ogunloye, Akimosa, Ibiyemi, Adebajo, Matimoju, Adeniyi, Isiyemi, Igbalu, Oresanya and Idewu Ojulari. Out of his children, Kosoko and Idewu-Ojulari became obas of Lagos. Idewu Ojulari was not survived by any child, thus leaving the Royal Family with 15 existing lineages.
THE GENEALOGY OF ESINLOKUN DYNASTY OF THE ROYAL HOUSE OF LAGOS
ORIKI ESINLOKUN
Esinlokun Ogbolu Maja, Baba gbele orikeki doyi,Oba Ajo fun won gbon ogi danu,Oba, tiko di ogan, ti ko di osun, Baba foro gbogbo jareO ja re odale, oja re eke, o ko bi fun osika,O ni kio wure pare eOmo atu-jabaju, Omo e fufu oro,Oba agboro yemo bi olodunmare,Oba bi olode oku, ode o gbodo wu gbegi,Oba to yi nile to ta mora,Omo asin wini joye,Oba orowini jiwini;Afinju Oba to gbe ori obinrin jo gbedu;Oba okiki nita Apa, Igba yinOgorun to ku o si timu.O pa eran bo ifa o pa eran bori,O se eyin aro gelemo gelemo;Oba okoroboto to soju ode de;Oba ti, nje Kutere asa logun,Ti orisa ba mbeOba Kutere ki ngbo,
Omo lroko Lado,Omo Epo werewere Lode IladoWon ki fi oko ro, won ki fi a da ro,Bi o ro, bi o ro, o ku gbodo kuro nibe,Afinju Alejo to nperan fun onile je,Omo Ajidagba bi Ogede,O da gba tan ara lowonOmo orogi raba, oro gbegbe Ajina,Omo liwe likoro Sangan we edu,Omo Ominla so pa kere;Omo Ogbinla ba gbo timutimu,Omo oni gbegbe Ajina.
ORIKI ODUNSI
Omo Abudu Kabasi,Olowo se wun gbogbo tan, oku te lenu;Abudu Kabasi bo lowo, ohun gbogbo gbesi ni,Bo lowo, ohun gbogbo gbesi niBo bi omo, ohun gbogbo gbesi niAbudu se ile iya dun moran moran,Baba YERINSA se la Baba bi afara oyin,Abudu ni bi ibi ote,Bi ibi owo eniti a ba niwaju to baba se;Bi ibi bate, bi ibi ba si wo,Onikuluku a majola Baba re.
Sources:
Wikipedia: Oba of LagosNews paper Obituaries IWUYE CEREMONIES Booklet of Chief Folarin Awobo Pearse as Aremo Oba of Lagos. Chief (Mrs.) Bolaji Aduke Pearse as Aladegboye of Lagos and Chief (Mrs.) Modupe Mojisola Williams as the Aladeniwa of Lagos. Please forward any important omitted informations or additional resources to our contact or comments section.
SUBSCRIBE TO ILEODUDUWA.COM